Have questions and need help?
support@ebooks2go.com

Òkú Ààrin Gbùngbùn 2: Kódà Nǹkan Tí Kò Dára Le Dára Bákannáà, Nigbàmíràn!

Overview

Publisher
Tektime
Released
July 11, 2024
ISBN
9788835465775
Format
ePub
Category
Fantasy

Book Details

Awọn Ṣẹrubani kọlu awọn Ẹmbasi Gẹẹsi ati Amẹrika ni Bangkok ni asiko kan na ti wọn si se ibajẹ lọpọlọpọ, sugbọn awọn wo ni wọn se isẹ yi, ati bawo ni a se le dáwọn duro lati mase se bẹẹ mọ?

Author Description

NIPA ÒNKỌ̀`WÉ NÁÀ
Ònkọ'wé Owen Jones, lati Bary, Gusu Wales, bẹrẹ iwe kikọ laipẹ yi, botilẹjẹwipé ó ti nkọwé lati igba ti ó ti dàgbà. Ó ti gbé ni ọpọlọpọ orilẹ-èdè nibiti ó ti sisẹ, 'si ti rin irinajo lọ si ọpọlọpọ orilẹ-èdè miràn si i.
Ó máa nsọ, tabi ó gbọ awọn èdè méje dáadáa, bẹẹ ni ó si nkọ lati mọ èdè Thai bayi, niwọn igbati ó ngbé ni Thailand pẹlu iyawo rẹ ọdun mẹwa.
"Kì í gba mi ni akoko pupọ lati mọ èdè kan," ni ó sọ, :sugbọn Thai kò ni ibasepọ pẹlu èdè miràn ti mo ti mọ ri." Nigbati wọn bi i léré nipa àrà iwe kikọ rẹ, ó wipé, "Celt ni mi, a si Romantiki. Mo gbagbọ ninu àtúnwá ati ohun pupọ nipa iyẹn. Awọn igbagbọ yẹn, bi 'Se si ẹlomiran...', ati 'Lááláá tó ròkè ilẹ ló nbọ', Àyànmọ ati Kama jẹ kókó si ayé mi, nitorina wọn farahàn ninu isẹ mi'.
Ìwé rẹ̀ akọkọ, 'Isẹ Asenajú Baba'(Daddy's Hobby) latinu awọn àtòjọ 'Lẹhin Ẹrin-musẹ: Itan Lek, Osisẹ Ọmọbirin nile Imuti ni Pattaya' ti ni awọn atẹ̀lé mẹrin, sugbọn eyi ti ó tobi julọ ni 'Awọn Atojọ Megan', awọn iwe mejidinlógún lori idagbasoke ọkàn ọmọbirin àgunbanirọ kan, eyi ti àkòri kukuru rẹ jẹ, 'Atọnisọna Ẹmi Kan, Ẹkun Ẹmi Kan ati Iya Abanilẹru Kan!' se àkótan gbogbo wọn dáadáa.
Gẹgẹbi Owen se salaye rẹ:
'Tí a Bi ni ilẹ̀ Orin,
Ti Ngbé ni Ilẹ Ẹrin'.

Read this book in our EasyReadz App for Mobile or Tablet devices

To read this book on Windows or Mac based desktops or laptops:

Recently viewed Books

Help make us better

We’re always looking for ways to improve. If you’ve got feedback or suggestions about how we can do better, we’d love to hear from you.

Note: If you’re looking to solve a problem with your URMS eReader, app, or purchase, visit our Help page, or submit a help request.

What is the purpose of your visit?
Did you accomplish your goal?
Yes No
Where can we improve?
Your comments*